Ọ̀ṣúnbùnmí

Pronunciation



Meaning of Ọ̀ṣúnbùnmí

Ọ̀ṣun gifted me (this child).



Morphology

ọ̀ṣun-bùn-mí



Gloss

ọ̀ṣun - Ọ̀ṣun, Yoruba river goddess of fertility and beauty
bùn - give
- me


Geolocation

Common in:
GENERAL



Variants

Bùnmí