Ọ̀ṣúnbùnmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣúnbùnmí
Ọ̀ṣun gifted me (this child).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣun-bùn-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣun - Ọ̀ṣun, Yoruba river goddess of fertility and beautybùn - give
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL