oyinadeoluwa

Sísọ síta



Ìtumọọ oyinadeoluwa

The sweetness of the crown of God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyin-adé-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyin - honey, sweetness
adé - crown, royalty
olúwa - God, Lord


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Oyinadé