Yíwọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Yíwọlá
Roll into success.
Àwọn àlàyé mìíràn
Also: Láyí, Láí, Láíwọlá, Láyíwọlá
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
yí-wọ-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
yí - rollwọ - enter
ọlá - success, wealth, notability
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL