Yeyérínsá
Sísọ síta
Ìtumọọ Yeyérínsá
Mother saw me and fled.
Àwọn àlàyé mìíràn
A name given to the child born before/after the immediate departure of a family matriarch. See: Babárínsá
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
yèyé-rí-mi-sá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
yèyé - motherrí - see, find
mi - me
sá - flee
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL