Yésìdé

Sísọ síta



Ìtumọọ Yésìdé

Mother returns still.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(i)yé-sì-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

iye - mother
sì - still
dé - return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Yétúndé