Yékú

Sísọ síta



Ìtumọọ Yékú

Stop dying.



Àwọn àlàyé mìíràn

It is most likely a name given to a child believed to have followed a long line of àbikú children who die as soon as they're born. 'Yeku is an imperative to "stop dying." It is probably a wrong spelling my ancestors settled for but it is different from "Ọ̀yẹ̀kú" (of the Ifa, for example). It is NOT a short form.' - James Yékú



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

yé-kú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

yé - stop
kú - die


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Oládàpọ̀ Yékú

  • Medical Oncology Fellow at Memorial Sloan Kettering Cancer Center

  • USA



Ibi tí a ti lè kà síi



Irúurú

Yẹkú

Kúyẹ̀