Yọ̀sóore

Sísọ síta



Ìtumọọ Yọ̀sóore

I rejoice in (the) goodness (of God). A short form of Moyọ̀sóoreolúwa



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

yọ̀-sí-oore



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

yọ̀ - rejoice
- into
oore - goodness, gift, benevolence, favour


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Moyọ̀sóoreolúwa

Moyọ̀

Moyọ̀soore

Yọ̀sóoreolúwa