Yẹmídalẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Yẹmídalẹ́

May I remain graceful until old age.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

yẹ-mí-di-alẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

yẹ - befit
mí - me
di - until
alẹ́ - evening, night, old age


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Yẹmí

Dalẹ́