Wíndàpọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Wíndàpọ̀

(Two) Forest fairies collide.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(i)wín-dàpọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

iwin - a forest fairy in Yorùbá mythology believed to live in teh ground
dàpọ̀ - mixed together, joined together, meet


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Iwíndàpọ̀

Dàpọ̀