Wọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Wọlá

Enters wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

wọ-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

wọ̀ - enter
ọlá - wealth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adéwọlá

Olúwọlá.