Wọ̀sọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Wọ̀sọ́lá

Settle into wealth/success.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

wọ̀-sí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

wọ̀ - enter, settle in
sí - into
ọlá - wealth, success, luxury


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IGBOMINA