Túnráyọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Túnráyọ̀

(I've) seen joy again.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

tún-rí-ayọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

tún - again
rí - see, find
ayọ̀ - joy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Motúnráyọ̀

Ráyọ̀