Tósìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Tósìn
Enough to worship.
Àwọn àlàyé mìíràn
This is a common short form of the name "Olúwatósìn".
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
tó-sìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
tó - enough forsìn - worship
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL