Tóminíyì

Sísọ síta



Ìtumọọ Tóminíyì

[This is] enough for my honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

tó-mi-ní-íyì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

tó - enough for
mi - me
ní - for
iyì - honour, respect