Tiwanijésù

Sísọ síta



Ìtumọọ Tiwanijésù

Jesus is for us.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

tiwa-ni-jésù



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

tiwa - ours
ni - is
jésù - Jesus


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA
FOREIGN-GENERAL