Tiwaloreọ̀fẹ́olúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Tiwaloreọ̀fẹ́olúwa

The grace of God is ours.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Tiwaniooreọ̀fẹ́olúwa.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

tiwa-ni-oore-ọ̀fẹ́-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

tiwa - ours
ni - is
oore-ọ̀fẹ́ - grace
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL