Titolújù
Sísọ síta
Ìtumọọ Titolújù
God's will is the most prominent/important.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ti-ti-olú-jù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
titi - belonging toolú - olúwa, lord, God
jù - be prominent, be important
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
EKO
GENERAL