Títóbilolúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Títóbilolúwa

Great is the lord.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

títóbi-ni-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

títóbi - greatness
ni - is
olúwa - the lord


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL