Títílayọ̀miníwájúolúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Títílayọ̀miníwájúolúwa

With God, I can always count on joy. Joy is established for me with God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

títí-ni-ayọ̀-mi-ní-iwájú-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

títí - forever, until
ni - is
ayọ̀ - joy, celebration
mi - my
ní - at
iwájú - in front of
olúwa - God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Títílayọ̀

Títílayọ̀mi