Tìmẹ́hìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Tìmẹ́hìn

To support (me), a shortening of names like Adétìmẹ́hìn, Olútìmẹ́hìn, Ògúntìmẹ́hìn, Fátìmẹ́hìn, etc.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

tì-mọ́-ẹ̀hìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- support, push
mọ́ - with, onto
ẹ̀hìn - back, behind, legacy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Tìmẹ́yìn

Tìmẹ́hìntì