Tèmídáre

Sísọ síta



Ìtumọọ Tèmídáre

Mine has turned to victory; Mine has become justified.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

Tèmí-di-áre, Tèmí-dá-àre



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

tèmi - mine
di - become(s)
àre - win/goodness/victory
tèmi - mine
dá...àre - justifies


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dáre