Tajélawí

Sísọ síta



Ìtumọọ Tajélawí

Let talk about business or trade.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ti-ajé-ni-a-wí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ti - of, belonging to
ajé - business, trade, enterprise
ni - is
a - we
wí - speak, say, talk about


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU