Tẹ́jú
Sísọ síta
Ìtumọọ Tẹ́jú
Calm on the surface.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
tẹ́-ojú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
tẹ́ - spread, calm (tẹ́rẹrẹ)ojú - face, surface
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Tẹ́jú Cole (born Ọbáyẹmí Babájídé Adétòkunbọ̀ Ọnàfuwà) Nigerian-American writer and novelist.