Tẹ́júoṣó

Sísọ síta



Ìtumọọ Tẹ́júoṣó

The one who calms the face of the sorcerer



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

tẹ́-ojú-oṣó



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

tẹ́ - to spread, to be calm (tẹ́rẹrẹ)
ojú - face
oṣó - sorcerer, òrìṣà oko, the god of fertility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
ABEOKUTA



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Adédàpọ̀ Tẹ́júoṣó

  • Ọ̀ṣilẹ̀ of Òkè-Ọ̀nà Abẹ́òkúta



Irúurú

Tẹ́júoshó