Súnmisọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Súnmisọ́lá

Move me towards honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

sún-mi-sí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

sún - shift, move, expand
mi - me
- into
ọlá - wealth, prestige, honour, nobility, benefit


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Súmi

Súnmi

Mosúnmọ́lá

Ọmọ́súnmisọ́lá