Ṣólàjà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣólàjà

The sorcerers have settled the fight.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣó-là-ìjà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, the god of farming
- split, part, settle, intervene
ìjà - fight, struggle


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Oṣólàjà

Shólàjà.