Sógbẹ̀hìndé

Sísọ síta



Ìtumọọ Sógbẹ̀hìndé

The sorcerer came back in the end.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

osó-gba-ẹyìn-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

osó - sorcerer
gbà - take
ẹyìn - back, future
dé - return, arrive