Simisólúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Simisólúwa

Rest in God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

sinmi-sí-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

sinmi - rest
- into
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OSUN



Irúurú

Sinmisólú

Sinmisólúwa

Sinmi