Shónibárẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Shónibárẹ́
It is the sorcerer that I befriended.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-ni-mo-bá-rẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, fertility god (Òrìṣàoko)ni - is
mo - I
bá - together with
rẹ́ - to be friendly with, to be acquainted to
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Yínká Shónibárẹ́
British-Nigerian artist