Shónáìkè

Sísọ síta



Ìtumọọ Shónáìkè

The sorcerer is famous.



Àwọn àlàyé mìíràn

The root oṣó has been interpreted most commonly in two ways: as sorcerer or wizard, but also as Òrìṣà Oko, the fertility god. Context is necessary to decide which one applies in individual cases.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(o)ṣó-ní-àìkè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, fertility god (òrìṣà oko)
ní - have
àìkè - notability, fame, òkìkí


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU
OGUN



Irúurú

Ṣónáìkè