Shónọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Shónọ́lá
The sorcerer (or the fertility deity) has honour. Also Oṣónọ́lá, Oṣólọ́lá, Oshónọ́lá, Oshólọ́lá, Ṣónọ́lá, Ṣólọ́lá...
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-ní-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, fertility god (Òrìṣà oko)ní - have
ọlá - honour, wealth, nobility, prestige
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
