Shónẹ́kàn
Sísọ síta
Ìtumọọ Shónẹ́kàn
The sorcerer has got an offshoot.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
(o)ṣó-ní-ẹkàn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, the divinity god (òrìṣà oko)ní - have
ẹ̀kàn - an offshoot
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Former (Interim) President Ernest Shónẹ́kàn.