Shómóyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Shómóyè
The god of the harvest chose the chief/taincy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-mú-oyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, fertility god (Òrìṣà oko)mú - to use; to hold (onto); to make, to bring, select
oyè - chieftaincy title, honor, prominence
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA