Shófọláhàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Shófọláhàn

The sorcerer unveils nobility.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(o)ṣó-fi-ọlá-hàn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, wizard
fi...hàn - expose
ọlá - wealth, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Fọláhàn