Shóbándé
Sísọ síta
Ìtumọọ Shóbándé
The deity of fertility has returned with me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-bá-n-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, Òrìṣaoko (fertility deity)bá - together with, to meet
n - me
dé - arrive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN