Shákúnlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Shákúnlé

Short form of Òrìṣàkúnlé: The Òrìṣà fills the house.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

òrìṣà-kún-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

òrìṣà - God
kún - fill
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IFE
OTHERS



Irúurú

Ṣákúnlé

Òrìṣàkúnlé

Kúnlé