Shẹ́nkòmayà

Sísọ síta



Ìtumọọ Shẹ́nkòmayà

Ùṣẹ̀n does not overwhelm me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ùṣẹ̀n-kò...láyà-m



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ùṣẹ̀n - Ùṣẹ̀n, an Ìjẹ̀bú ancestral deity
kò...láyà - weigh down, overwhelm
m - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Ṣẹ́nkòmaiyà

Ṣẹ́nkòmayà

Shẹ́nkòmaiyà