Shóníyan

Sísọ síta



Ìtumọọ Shóníyan

The sorcerer has a joyful swagger.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣó-ní-ìyan



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, the god of farming (Òrìṣà oko)
- have
ìyan - swagger


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Ṣóníyan

Níyan