Sáfẹ́jọ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Sáfẹ́jọ́

Flee(ing) from acrimony.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

sá-fún-ẹjọ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

sá - run, flee
fún - from
ẹjọ́ - acrimony, a court case


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Mosáfẹ́jọ́