Sọmídọ̀tun

Sísọ síta



Ìtumọọ Sọmídọ̀tun

Renew me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

sọ-mí-di-ọ̀tun



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

sọ - turn, make
mí - me
dì - to become
ọ̀tun - renewed


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Dọ̀tun