Rósanwó

Sísọ síta



Ìtumọọ Rósanwó

Wait enough to be able to pay.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(dú)ró-san-owó



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dúró - wait, stand, stop
san - pay
owó - money


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Sanwó