Ródẹmádé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ródẹmádé
(One who) adds brass (ornaments) to crows.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Asíndẹmádé
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ró-idẹ-mọ́-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ró - stand, wait (dúró)idẹ - brass
mọ́ - with
adé - crown
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU