Rìnlóyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Rìnlóyè

Walk to receive honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

rìn-ní-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

rìn - walk
ní - have
oyè - honour, chieftaincy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Arìnlóyè

Adérìnlóyè

Ọmọ́rìnlóyè