Rọ́mọkẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Rọ́mọkẹ́
Found a child to cherish.
Àwọn àlàyé mìíràn
A shortened form of "Morọ́mọkẹ́"
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-rí-ọmọ-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Irí - found, see
ọmọ - child
kẹ́ - cherish
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL