Rọ́lákẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Rọ́lákẹ́
I found a treasure to pamper/care for/shield.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
rí-ọlá-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
rí - see, findọlá - prestige, honour, wealth, nobility
kẹ́ - cherish, pamper, care for
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI