Powóọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Powóọlá
1. Call the money of honour. 2. Earn the money of houour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
pè-owó-ọlá, pa-owó-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
pè - to callowó - money
ọlá - wealth, nobility, honour, notability
pa - to do, to perform; to turn off; to kill; to change
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE