Pópóọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Pópóọlá

The avenue to success.



Àwọn àlàyé mìíràn

Full spelling: Òpópóọlá



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

pópó-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

pópó - road, street, avenue (òpópónà)
ọlá - success, wealth, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL