Pípéniṣẹ́olúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Pípéniṣẹ́olúwa

The work of God is complete.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

pípé-ni-iṣẹ́-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

pípé - complete
ni - is
iṣẹ́ - work, the doing
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL