Pípọ̀lọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Pípọ̀lọlá
(Our) success is plenteous.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
pípọ̀-ni-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
pípọ̀ - abundance, plentiful, púpọ̀ni - is
ọlá - wealth, nobility, notability, success
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO